Take a fresh look at your lifestyle.

‎’Super Eagles’ Bẹ̀rẹ̀ Ìgbaradì Fún Ìpele Oníkọ̀ Mẹ́rìndínlógún Tí AFCON 2025 ‎

104

 Bí Super Eagles ṣe ń múra sílẹ̀ fún ifẹsẹwọnsẹ wọn nínú ìdíje bọ́ọ̀lù Adúláwọ̀ “African Cup of Nations” (AFCON) ní ìpele oníkọ̀ mẹ́rìndínlógún pẹ̀lú Mozambique ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kìíní, ọdún 2026, àwọn òun márùn-ún wọ̀nyí ló ń ṣẹlẹ̀ sí ikọ náà ní àgọ́ wọn;

‎– Àwọn agbábọ́ọ̀lù malárùndínlọ́gbọ̀n ní wọn kopa nínú ìkọ́ni tí alẹ́ ọjọ́ Ẹtì

‎– Ryan Alebiosu wà ní ìpàgọ́ ẹgbẹ́ náà ṣùgbọ́n kò kópa latari ìlera rẹ̀.

‎– Ìpalára itan ti mú kí Cyriel Dessers kúrò nínú ìpàgọ́ ẹgbẹ́ náà. Ó ti padà sí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù rẹ̀ báyìí.

‎– Tochukwu Nnadi náà kó kópa latari àárẹ̀ ránpẹ́ tí òtútù.

‎– Olùkọ́ni àgbà Eric Chelle ti sọ fún àwọn agbábọ́ọ̀lù náà láti fi àwọn àṣeyọrí ìpele akọ́kọ́ sẹyìn kí wọ́n sì dojúkọ ìpele tó kù níwájú.

‎Super Eagle tí Nàìjíríà ní yóò waako pẹ̀lú Mòsámbìk ni ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kárún-ùn, oṣù kìíní, ọdún 2026.

Comments are closed.

button