Take a fresh look at your lifestyle.

FIFA Ṣàfihàn Orúkọ Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Tí Yóò Jẹ́ Olùdarí Eré Ìdárayá ti  2026

110

FIFA ti ṣe àkójọpọ̀ Orúkọ Àwọn Ọmọ Nàìjíríà tí yóò jẹ́ Olùdarí eré ìdárayá ní Àgbáyé ti ọdún 2026 ní gbángba, ó sì jẹ́rìí sí i pé àwọn ọgbọ̀n (30) ní a fọwọ́ sí láti dárí àwọn ìdíje àgbáyé ní onírúurú ẹ̀ka.

‎ Àkójọpọ̀ ọdọọdún náà ní a ti ṣafihan àwọn oludari náà àti àwọn amugba lẹgbẹ wọn ní a ti ṣe àyẹ̀wò wọn, tí a sì fún wọn ní àṣẹ láti ṣe àkóso àwọn ìdíje àgbáyé lábẹ́ CAF àti FIFA.

‎Aṣojú Nàìjíríà tí yóò máa ṣojú FIFA nínú àwọn ọkùnrin àti obìnrin nínú ìdíje bọ́ọ̀lù ẹlẹsẹ àti bọ́ọ̀lù etíkun tí ọdún 2026 ni;

‎ 1. Samuel Pwadutakam – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2014 – Okunrin

‎ 2. Ukah Ndubuisi Odigomma – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2014 – Okunrin

‎ 3. Musa Dung Davou – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2015 – Okunrin

‎ 4. Basheer Salisu – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2016 – Okunrin

‎ 5. Digbori Tejiri – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) 2016 – Okunrin

‎ 6. Fawole Olawale Adeolu – Olùdarí Bọ́ọ̀lù afẹsẹgba etikun (CAF) 2016 – Okunrin

‎ 7. Hannah Elaigwu – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2017 – Obìnrin

‎ 8. Ogabor Joseph Odey – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2017 – Okunrin

‎ 9. Usman Abdulmajeed Olaide – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2017 – Okunrin

‎ 10. Abdullahi Abubakar – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2018 – Okunrin

‎ 11. Olajide Olayinka – Olùdarí Bọ́ọ̀lù afẹsẹgba etikun (CAF) – 2018 – Okunrin

‎ 12. Nurudeen Abubakar – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2019 – Okunrin

‎ 13. Abibatu Iyadunni Stockl – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2019 – Obìnrin

‎ 14. Rabiu Ahmad – Olùdarí Bọ́ọ̀lù afẹsẹgba etikun (CAF) – 2019 – Okunrin

‎ 15. Mustapha Grema Mohammed – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2020 – Okunrin

‎ 16. Olufunmilayo Abigael Alaba – Referee (CAF) – 2020 – Obìnrin

‎ 17. Mfon Akpan – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2020 – Obinrin

‎ 18. Bello Zuru Alhassan – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2020 – Okunrin

‎ 19. Akintoye Yemisi – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2021 – Obìnrin

‎ 20. Terah Kabeda Beauty – Oniranlọwọ Olùdarí(CAF) – 2021 – Obinrin

‎ 21. Abdulsalam Kasimu Abiola – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2022 – Okunrin

‎ 22. Ahmad Mustapha Tijjani – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2023 – Okunrin

‎ 23. Muhammad Muhamud Yakubu – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2023 – Okunrin

‎ 24. Egba Patrick John – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2024 – Okunrin

‎ 25. Agbons Faith – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2024 – Obìnrin

‎ 26. Omada Emmanuel – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2025 – Okunrin

‎ 27. Ojeleye John Tope – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2025 – Okunrin

‎ 28. Adejoh Noah – Olùdarí Bọ́ọ̀lù afẹsẹgba etikun (CAF) – 2025 – Okunrin

‎ 29. Omotoye Tomilayo Oluwatosin – Olùdarí bọ́ọ̀lù orí pápá (CAF) – 2026 – Obìnrin

‎ 30. Lawal Ridwan Temitope – Oniranlọwọ Olùdarí (CAF) – 2026 – Okunrin.

‎ Awọn wọ̀nyí ní yóó máa tukọ àwọn ìdíje àgbáyé pàtàkì, àwọn ìdíje Áfíríkà, àti àwọn ìdíje jákèjádò kàlẹ́ńdà bọ́ọ̀lù 2026, èyí sì tún ń mú kí ẹsẹ̀ Nàìjíríà lágbára sí i lórí ìpele oludari awọn ìdíje àgbáyé.

Comments are closed.

button