Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Nwifuru Gbóríyìn Fún Àwọn Àṣeyọrí Ni Orísirísi Ọnà Ni Ìpínlẹ̀ Ebony.

170

Gómìnà Francis Nwifuru ti gbóríyìn fún àwọn àṣeyọrí àti àwọn ìdàgbàsókè to sẹlẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Ebony nipa ètò Ẹ̀kọ́ àti ìlera.

Nwifuru so èyí di mímọ̀ lásìkò to n ṣe idupẹ nile ìjósìn láti sààmì sí ayẹyẹ ọdun ìjọba awaarawa ni Abakaliki.

Gómìnà sàlàyé wí pé àwọn àtúnṣe àti ìdàgbàsókè ti ba àwọn agbègbè káàkiri nínú ìpínlẹ̀ náà ni èyí to mu inu oun dùn púpọ̀.

Ó ni àwọn iṣé yìí wà fún ìdàgbàsókè àti àtúnṣe àwọn ará ìlú pátápátá láti jẹ adun ètò ìjọba awarawa.

Ó ni nípa ètò ẹ̀kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ to lé ni Egberun Meji olè laadorin ni won ti jẹ anfààní eko ọfẹ ti ètò sí n tẹsiwaju sí.

Gómìnà ni nípa ètò ìlera àwọn ti fi kún owó àwọn dókítà to n ṣiṣe ni ilé ìwòsan ìjọba.

Gómìnà Nwifuru wa rọ àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà láti túbọ̀ kún fún ádùrá fún àwọn adarí wọn

Ó wá fi anfààní náà dupe púpò lówó Gómìnà Ana àti àwọn adari ìsìn.

Comments are closed.

button