Take a fresh look at your lifestyle.

Wọ́n Fi Ìbò Gbé Ààrẹ NFF Wọlé Gẹgẹ Bí Ààrẹ WAFU B

178

Alága àjọ Nigeria Premier Football League (NPFL), Otunba Gbenga Elegbeleye ti gbósùbà fún idibo ààrẹ àjọ Nigeria Football Federation (NFF) Alhaji Ibrahim Gusau sì ipò alàkóso CAF West Africa Football Union(WAFU) B. bi èyí to dára àti ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ ní ẹ̀ka òṣèlú eré bọọlu aláfẹsẹ̀ gbá.

 

Àjọ Confederation of Africa Football (CAF) ṣe ipín agbègbè ní ọnà láti máà darí àti ìwúlò wọn. Ipin WAFU B ní àwọn orílẹ̀-èdè bíi; Nigeria, Benin Republic, Burkina Faso, Cote d’Ivoire, Ghana, Niger Republic ati Togo.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button