Ààrẹ Banki Idagbasoke Isilaamu – “Islamic Development Bank” Muhammad Sulaiman Al Jass ti sọ pé Orílè-èdè Algeria yoo ri Biliọnu Mẹta Owó dọ́là ya laarin odun mẹta tẹ̀léra lati fi ṣe àwọn àkànṣe iṣẹ ìdàgbàsókè.
Ààrẹ ilè ifowopamọ, Al Jasser sọ pé, wọn yóò fi owó náà ṣe àkànṣe iṣẹ́ bíi ìtèsíwájú ọkọ̀ Reluwé gẹ́gẹ́ bí èròngbà ààrẹ láti so ẹ̀ka ọrọ̀ ajé papọ̀.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san