Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Nàìjíríà Ṣàtúnṣe Ìgbìmọ̀ Eré Ìdárayá Orílẹ̀-èdè Fún Ìlọsíwájú

Lekan Orenuga

96

Ààrẹ Bola Tinubu kéde àtúnṣe tí Ìgbìmọ̀ Eré Ìdárayá tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (National Sports Commission NSC) tó tí wá fún ìgbà pípẹ́ láti dáàbòbo ìṣàkóso eré ìdárayá kúrò lọ́wọ́ àwọn ìdádúró ìjọba àti àwọn ìdíwọ́ mìíràn.

‎ Ààrẹ ló sọ èyí nígbà tó kéde ìbẹ̀rẹ̀ eré ìdárayá tí Orílẹ̀-èdè ikejìlèlogún irú rẹ̀ ní àjọṣe àrà ọ̀tọ̀ tí wọ́n ń pè ní ‘Gateway Games Ogun 2024’ nílùú Abeokuta, Olú ìlú ìpínlẹ̀ Ogun.

‎ Ààrẹ náà tí igbákejì rẹ̀ Kashim Shettima sójú ní Abeokuta, sọ pé ìpinnu ìṣàkóso rẹ̀ yóò ṣé àfihàn ìṣàkóso pàtàkì fún àwọn eré ìdárayá Orílẹ̀-èdè nítorí ipá pàtàkì tí ẹka náà ń ṣé ní orílẹ-èdè.

Comments are closed.

button