Take a fresh look at your lifestyle.

Ó Léwu Láti Ṣe Ìtójú Ará Yìí Ẹ Ló Sì Ilé ìwòsan Fún Ìtọ́jú Tó Péye: Àwọn Onímọ̀

78

Ààrẹ fún ìtọ́jú agbègbè àti ìlera àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (EPHPAN)   Dọ́kita Samuel Akingbehin ti wọn jẹ onimọ ati olùtújù agbegbe ti ṣe ìkìlọ  àti ewu tó wà nínú ki àwọn ènìyàn má ṣe ìtọjú ará wọn Lai gbà aṣẹ lọwọ Oníṣègùn òyìnbó.

Akingbehin sọ èyí di mímọ̀ ni ọjọ́ Ìṣẹgun lásìkò tó ń ba ilé iṣé oníròyìn NAN sọ̀rọ̀.

Ó ní lílọ ògùn Lai gbà ìtoni àti ìtọ́nisọ́nà láti ọ̀dọ Oníṣègùn òyìnbó le ṣe àkóbá nlá fún ìlera, pàápàá jùlọ àwọn aláboyún.

Ó ní lílọ ògùn àti asilo ògùn le mú kí ènìyàn pàdánù emi rẹ.

Ó wa rọ àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti lò fún àyẹ̀wò ni ilé ìwòsan kí wọn sí Dọ́kítà fún itona ogun ti wọn ló.

Comments are closed.

button