Take a fresh look at your lifestyle.

Orílè-èdè Sierra Leone Ṣe Ìkìlọ Nlá Fún ilẹ Áfíríkà Nípa Àìsàn Mpox.

62

Látàrí àìsàn tí wọn n pé Mpox Orílẹ-èdè Sierra Leone ti ké sita fún àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà láti ni akiyesi nlá nítorí àìsàn náà gbilẹ báyìí.

Wọn ní kí àjọ eleto ìlera ni akiyesi pàtàkì kí àìsàn náà wà ba gbilẹ sí.

Dọ́kítà Ngashi Ngongo ló sọ èyí dì mimọ lásìkò to n sàlàyé ìròyìn nípa àìsàn àti bí ètò ìlera ṣe nlọ ni ọjọ́ ẹtì.

Àjọ ìlera àgbáyé (WHO) sàlàyé wí pé àìsàn Mpox yìí jẹ àìsàn to ma n ra láti ara elomiran sí ẹnìkejì.

Wọn ni báyìí àwọn ènìyàn n fi ara ko, ti o sí gbilẹ káàkiri nítorí àkọsílẹ n pósí lojojumo.

Wọn àwọn àpẹrẹ tí yóò ma mú wá ni o, o tun tun, ará gbígbóná, ibà àti bebelo

Wọn kí àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà ni àkíyèsí ara fún àìsàn náà, ti ba sí ko firi ohun kan kí wọn tètè fi to àjọ eleto ìlera létí.

Comments are closed.

button