Ilé-iṣẹ́ tí Ìròyìn àti àlàyé tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí bẹ̀rẹ̀ àtúnyẹwò iṣẹ́ ìdá Kejì nínú ọdún ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìlànà tí a ti ṣètò nípasẹ̀ ‘Central Delivery Coordinating Unit’ CDCU ní ilé-iṣẹ́ Ààrẹ.
Nígbàtí o n sọrọ ní àpéjọ àtúnyẹwò ní Abuja, Mínísítà fún Ìròyìn àti Àlàyé tí Orílẹ̀-èdè, Mohammed Idris, sọ pé àpéjọ náà ní a pé ní atẹle sí àwọn ìwé àdéhùn iṣẹ́ tó f’ọwọ́ sí láàrin òun àti Àwọn olórí Àwọn Ẹká lábẹ́ àwọn Ilé-iṣẹ́ ní Oṣù Kẹjọ ọdún 2024.
Ọ̀gbẹ́ni Idris ṣé àkíyèsí pé tẹlé tí ìfọ́wọ́ sí ìwé àdéhùn iṣẹ́ pẹ̀lú Ààrẹ Tinubu lórí ìṣẹ́ àwọn ilé-iṣẹ́.
Comments are closed.