Ayé n dúró dè àbájáde ìfilọ́lẹ̀ Olórí Kátólìkì Túntún, tó bẹ̀rẹ ní ọjọ́ kéje Oṣù Kàrún ọdún 2025, bí àwọn kadinali ṣé pejọ ní ‘Vatican’ láti yán olórí tí Kátólìkì.
Ikú Pope Francis ní ọjọ́ kọkanlelogun, Oṣù Kẹ́rin, ọdún 2025, ní ẹni ọdún mejidinlaadọrun (88).

Ìjọba ọdún méjìlá rẹ̀ jẹ́ èyí tó f’ayé gbá ìrẹlẹ, Ìfarádà àti àtúnṣe. Àmì lórí Ile-ijọsin káàkiri àgbáyé.
Gẹ́gẹ́bí Pópù àkọ́kọ́ tó jẹ Látìnì Amẹ́ríkà tí kìí ṣé ọmọ ilẹ̀ Yúrópù lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún.
Ó bẹ̀rẹ olórí ìjọ kátólìkì náà ní ọdún 2013
Comments are closed.