Take a fresh look at your lifestyle.

Owó Orí Ọjà Amẹ́ríkà Dẹ́rùba Ọrọ̀ Ajé Ilẹ̀ Adúláwọ̀ -Akọ́sẹ́mọsẹ́ Ọmọ Orílẹ̀-èdè Màláwì

249

 

Owó orí ọjà Amẹ́ríkà lórí ọrọ̀ ajé ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ sàkóbá bá ọrọ̀ ajé wọn, orílẹ̀-èdè Màláwì jẹ́ ọ̀kan, akọ́sẹ́mọ́sẹ́ nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú-Maclan Kanyang’wa sọ èyí.

 

Ó sọ pé, oye owó tí wọ́n ń ta nǹkan ní àwọn orílẹ̀-èdè ti kò ti gòkè àgbà yóò lọ sókè látàrí ìgbésẹ Amerika, ọrọ yóò dẹnu kolẹ̀

 

Bí wọ́n ṣe kò àwọn èròjà tí wọ́n fi ń ṣe nǹkan káàkiri láàrin ara wọn ní ìlú to ṣẹ̀ṣẹ̀ ń gòkè àgbà yóò forísánpọ́n látàrí àwọn owó ori yìí, látàrí èyí àwọn orílẹ̀-èdè wọnyí yóò gbè ọjà díẹ̀ lọ sí òkè òkun eléyìí yóò mú ìlọsilẹ̀ bá ọrọ̀ ajé orílè-èdè náà.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button