Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé iṣé NNPC Foundation Ti Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Iṣé Abẹ Ọfẹ Fún Àìsàn Ojú Ni Ìpínlẹ̀ Niger.

70

Ilé iṣé NNPC Foundation ti ṣe ètò ìtọ́jú iṣé abẹ ọfẹ fún àìsàn ojú fún àwọn ènìyàn Ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta ni ìpínlẹ̀ Niger.

Iyaafin Emmanuela Arukwe tó jẹ adari àgbà pátápátá fún ilẹ Isé NNPC Foundation ló sọ èyí di mímọ̀ ni Minna ni ọjọ ẹti.

Arukwe ti Alaaji Adamu Sani sojú fún sọ wí pé ẹrọngba àwọn ní láti ṣe toju àwọn ènìyàn ti o ni àìsàn ojú kí wọn sí wa ni ipò Àlàáfíà lásìkò

Ó ni àìsàn ojú tí wọn ní pa Cataracts to ṣe àkóbá nlá fún àwọn ènìyàn Orílè-èdè yìí púpò ìdí níyì ti àwọn fi mú ètò náà wà.

Ó ni ètò náà wà fún gbogb àwọn ènìyàn pátápátá pàápàá jùlọ ẹnikẹni tó bá tètè de yóò jẹ anfààní nlá.

Comments are closed.

button