Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Àrin rìn Mẹfa Ló Jade láyé Ní Agbègbè Libyan.

72

Ó kéré ju àwọn àrin rìn àjò méfà ni o jáde láyé ní agbègbè Libyan Misrata.

Gẹgẹ bí ẹní ti ìròyìn náà soju rẹ, wọn ni àwọn ìjàmbá tó n ma wáyé ni èyí látàrí bi àwọn àrin rìn àjò ba fẹ ló sì Orílè-èdè Europe nígbà tí wọn bá gbà láti làá òkun pupa kọjá.

Makhlouf Karimi to jẹ olori àwọn ti n mójú tó ìjàmbá eti òkun pupa, sàlàyé wí pé òkú ènìyàn mẹrin ni wọn sí gbé jade ni àárò ọjọ́rú tí wọn sí wọn gbé méjì jade ni irọlẹ Ojo náà.

Won ni ojú ònà yìí ni àwon ènìyàn ma n Saba gbà koja, pàápàá jùlọ àwọn àrin àjọ.

Comments are closed.

button