Take a fresh look at your lifestyle.

Lójúnà Àti Sọ Ayé Di Gbẹdẹmukẹ, Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Se Àtìlẹyìn Fún Ará Ìlú

97

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara fi àrídájú hàn sí àwọn olùgbé Ìpínlẹ̀ náà wípé jíjẹ mùdùn-múdùn ìdókoòwò ìjọba yóò tẹ̀síwájú èyí tí yóò sọ ayé di gbẹdẹmukẹ ní Ìpínlẹ̀ Kwara

 

Alága Ètò Ìdókóòwò ní Ìpínlẹ̀ Kwara, Ọ̀mọ̀wé Abdulwasiu Ọlayinka Tejidini ni ó fi àrídájú náà léde níbi àpérò kan tí ó wáyé láàrin àwọn ẹka ìjọba ní gbọ̀ngàn ilé iṣẹ́ ìjọba ní Ìpínlẹ̀ Kwara

 

Tejidini sọ pé àjọ náà ń gbèrò láti na ọwọ́jà ètò náà káàkiri èyí tí yóò se àtìlẹyìn owó fun awọn eniyan jákè-jádò ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rìndínlógún tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Kwara

 

 

 

Comments are closed.

button