Take a fresh look at your lifestyle.

Àyájọ́ Òsìṣẹ́: Adarí Ilé Asòfin Jẹ́jẹ̀ẹ́ Ìbásepọ̀ Tí Ó Gún Régé Pẹ̀lú Àjọ Òsìṣẹ́

63

Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin, Godswill Akpabio ti jẹ́jẹ̀ẹ́ pé ilé ìgbìmọ̀ Asòfin ẹlẹ́kẹ̀ẹwàá lábẹ́ ìsàkóso òun yóò ní ìbásepọ̀ tí ó dán mọ́rán gẹ́gẹ́ bí ó se sọ lásìkò àyájọ́ òsìṣẹ́

 

Ó gbósùbà fún àjọ Òsìṣẹ́ fún iṣẹ́ takun-takun tí wọ ń se, ìfarajì àti ìdúró sinsin, papàá jùlọ lásìkò tí Orílẹ̀-èdè ń dojú kọ àwọn ìpèníjà ọlọ́kan-ò-jọ̀kan

 

Akpbio sọ ọ̀rọ̀ náà nínú àtẹ̀jáde kàn tí olùbádámọ̀ràn pàtàkì lórí ìròyìn àti ìfọ̀rọ̀léde sí i , Ọ̀gbẹ́ni Eseme Eyiboh fi léde. Ó sàdéhùn pé ìgbáyégbádùn, ààbò, ìgbégà lẹ́nu iṣẹ́ fún àwọn òsìṣẹ́ yóò jẹ́ ohun àmójútó

 

 

 

 

 

 

 

 

Comments are closed.

button