Take a fresh look at your lifestyle.

Davido Gba Àmì Ẹ̀yẹ Headies award Ẹlẹ́ẹkẹtàdínlógún Akọrin Òrí Ayélujára Tó Dára Jùlọ

195

Gbajúmọ̀ Ìràwọ akọrin tàkasùfé ọmọ orílẹ̀-èdè yìí, David Adeleke, tó ti gbá ọpọ àmì ẹ̀yẹ ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sì Davido ti gba àmì ẹ̀yẹ Headies award Ẹlẹẹkẹtadinlogun akọrin orí Ayelujara to dára jùlọ ti ọdún yìí.

Àwo rẹ bii “Ogechi Remix” pẹ̀lú Hyce, Boypee, àti Brown Joel ní wọ́n tún fọwọ́ sì fún yíyn ìfagagbága ní ojó Àìkú ọjó kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù kẹrin ọdún 2025 ní gbọ̀ngán Landmark Event Centre, ìlú Èkó, ipinlẹ Eko.

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìràwọ akọrin ló péjọpọ̀ síbi ayẹyẹ tó ga náà. Àwọn míràn tó tún gba àmì ẹ̀yẹ láti ri; Zerry DL, Tems, Funke Akindele, àti Rema.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button