Mínísítà Gbóríyìn Fún Àwọn Ẹṣọ Ghana Kán Fún Ìgbàlà Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Ogún-lugba-Dín-Kán
Lekan Orenuga
Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ fún ètò Ọrọ òkèèrè, Bianca Odumegwu-Ojukwu, tí gbóríyìn fún àwọn aláṣẹ orílẹ-èdè Ghana fún Ìgbàlà àwọn ọdọ Nàìjíríà Ogún-lugba-Dín-Kán (219) tí wọ́n gbé lọsí orílẹ-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà náà tí wọ́n sí fí ipá mú wọ́n látí máà ṣé ìjàmbá lórí ayélujára.
![]()
O tún wá fí ìpinnu ìṣàkóso Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu hàn láti pèsè iṣẹ́ fún àwọn ọdọ ní pàápàá ẹ̀kọ́ imọ-ẹrọ àti ọgbọ̀n látí dènà áìníṣẹ́ tí n dàgbà sí.
![]()
Mínísítà náà sọ àwọn wọ̀nyí nígbàtí o ṣé àbẹwò sí Ilé-iṣẹ́ ìwà ajẹbanu (Economic and Organised Crimes Office EOCO) ní Accra, Ghana, níbití àwọn wọ̀nyí wà ní atimọle.