Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdásílẹ̀ Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ní Yóò Fí Òpin Sí Rògbòdìyàn Ètò Ààbò – Gómìnà Sani

Lekan Orenuga

83

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna, Uba Sani, sọ pé ìdásílẹ̀ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ ní yóó fí òpin sí àwọn ìpèníjà ààbò tó ń wáyé ní gbogbo àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rin-dín-logójì (36) tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

‎ Gómìnà Uba, tó sọ èyí níbí ifọrọwanilẹnuwo kán ní Abuja, ní ẹgbẹ kán níbí ìpàdé ẹgbẹ́ àwọn Gómìnà Nàìjíríà, ṣé àfihàn àwọn idiwọn tó ń dojukọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀.

‎ Nítorí náà Gómìnà náà pé fún àjọṣepọ̀ láàrín àwon Gómìnà látí kojú àwọn ìpèníjà ààbò tó ń dojú kọ́ Ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan láti farahàn gẹ́gẹ́ bí aṣiwaju réré.

Comments are closed.

button