Take a fresh look at your lifestyle.

Ezigbo Gbé Pẹ́rẹ́gi Ìjà Kaná Pẹ̀lú Ẹgbẹ́ APC Ní Ìpínlẹ̀ Anambra

104

Ọ̀gbẹ́ni Valentine Ozigbo tí ó jẹ́ olùdíje nínú ìdìbò abẹ́le ẹgbẹ́ òsèlú APC fún ìgbáradì láti kópa nínú ìdíje sí ipò Gómìnà ní Ìpínlẹ̀ Anambra ti gbé ẹgbẹ́ òsèlú APC lọ sí ilé ẹjọ́ gíga ní ìlú Awka látàrí ìfẹ̀hónúhàn lórí àbájáde ìdìbò abẹ́lé tí ó wáyé ní ọjọ́ Karùn-ún osù kẹrin ọdún 2025

 

Ó pè fún fífagilé kíkéde Ukachukwu gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó jáwé olúborí nínú ìdìbò abẹ́lé náà àtipé Ozigbo ni ẹni tí ó tọ́ láti kéde, nígbà tí ó sàpèjúwe ètò ìdìbò náà gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó ní mọ̀kàrúrù nínú

 

Ọ̀gbẹ́ni Valentine sàpèjúwe ìgbésẹ̀ náà gẹ́gẹ́ bí èyí tí yóò mú ìtẹ̀síwájú bá ìjọba tiwa-n-tiwa, tí yóò sì fi ìdí ìdájọ́ òdodo rinlẹ̀

 

 

 

Comments are closed.

button