Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Ààrẹ Shettima Ṣe Ìkini Ẹ Pẹlẹ Sí Ilè Olóògbé Gbemisola Olowolafe.

85

Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kashim Shettima ti ṣe ìbẹ̀wọ̀ sí ilè olóògbé Iyaafin Gbemisola Olowolafe.

Ó ṣe àpèjúwe olóògbé náà gẹ́gẹ́ bí ẹní tó ṣe iṣé rẹ dé ojú ààmì to sí fi ará rẹ jì fún ìdàgbàsókè iṣé ìjọba

Olóògbé Iyaafin Gbemisola Olowolafe jẹ ìyàwó adarí Fásítì ìpínlẹ̀ Ekiti àti Ààrẹ ilé iṣé GZ.

Níbi ayẹyẹ ètò ìsìn idagbere, igbákejì Ààrẹ ṣe àpèjúwe rẹ gẹ́gẹ́ bí Obìnrin tó ṣe fèyítí, to dúró ti oko, to sí fi àwọn tó yí kà ṣọkan.

Ó wa rọ àwọn ènìyàn láti ko ẹkọ réré lára olóògbé náà , nitori o jẹ Eni ti o ni ìfẹ gbogbo àwọn ènìyàn tó yí kà pátápátá.

Comments are closed.

button