Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ní ọjọ́rú ọjọ́ Kejì oṣù kẹrin ọdún 2025 yóò kúrò ni Abuja lọ sí Orílẹ-èdè France fún ìbẹ̀wọ̀ ránpẹ́ nípa iṣé.
Nínú àtẹ̀jáde kan láti ọwọ́ agbẹnusọ fún Ààrẹ, Ọ̀gbẹni Bayo Onanuga ló sọ èyí di mímọ̀.
Ó ní Ààrẹ yóò sọ èròngbà ìjọba re àti ìdàgbàsókè èyí tí yóò wáyé ninu ìjọba rẹ.
Ó ni àwọn èròngbà àti ètò to ní nínú ìjọba re yóò di mímọ̀ fún àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti France.
Nígbà tí kò sí nílé báyìí àwọn òṣìṣẹ́ abáni ṣíṣe pọ yóò díle mú Títí yóò fi dè láti ti mójú tó ètò ìjọba.
Ààrẹ yóò Títí Ọjọ́ Àbámẹ́ta.