Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ EFCC Pàrọwà Sí Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Láti Jìnà Sí Ìwà Àjẹbánu Lójúná Àti Mú Ìdàgbasókè Bá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

88

 Àjọ EFCC ti pàrọwà sí àwọn akékọ̀ọ́ láti kó ipa tí ó làmì laaka lójúnà àti gbógunti ìwà àjẹbánu èyí tí ó sàfihàn irúfẹ́ ìgbésẹ̀ bẹ́ẹ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

 

Alága Àjọ EFCC, Ọ̀gbẹ́ni Ọlá Olúkáyọ̀dé ni ó pa àrọwà náà nígbà tí ó ń se ìfilọ́lẹ̀ ètò fun àwọn akẹ́kọ̀ọ́ èyí tí ó kó ilé ẹ̀kọ́ mọ́kànlá sínú ní ìlú Abuja, Olú Ìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

 

Ọgbẹ́ni Olukayọde sọ pàtàkì ìwà àpọ́nlé, òdodo, àti àmójútó àwùjọ láàrin àwọn ọ̀dọ́ gẹ́gẹ́ bí èyí tí yóò mú kí ọjọ́  iwájú Orilẹ-ede Naijiria dara

Comments are closed.

button