Take a fresh look at your lifestyle.

Àbádòfin Fún Ìdásílẹ̀ Àjọ Elétò Ìdìbò Ti Ìjọba Ìbílẹ̀ Ń Tẹ̀síwájú Ní Ilé Asòfin

91

Àbádòfin fún ìdásílẹ̀ àjọ ìsàkóso ètò ìdìbò sí àwọn ìjọba ìbílẹ̀ gbogbo ni ó ti kọjá ìpele kejì ní ilé asòfin

 

Àbádòfin náà ní àfojúsùn fún ìdásílẹ̀ àjọ kan fún ìsàkóso ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ jákè-jádò Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

 

Igbákejì adarí Ilé Asòfin, Benjamin Kalu ni ó se agbátẹrù  àbádòfin náà àti àwọn mẹ́jọ míràn

 

Ìrètí wà pé àjọ náà yóò ní alága àti ọmọ ìgbìmọ̀ mẹ́tàdínlógójì, èyí tí yóò sojú ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan àti olú ìlú Orílẹ̀-èdè Naijiria

 

Comments are closed.

button