Take a fresh look at your lifestyle.

Ayẹyẹ Eré Ìdárayá ti ikejilelogun Irú Rẹ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu Tan Ina Ìdárayá.

94

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti ran ina oya kí eré bèrè ti ikejilelogun Irú rẹ tí yóò wáyé káàkiri àwọn Ìpínlẹ̀ merindinlogoji àti ìlú Abuja.

Aare Tinubu tan Ina Ìdárayá náà ni ilé ìjọba ni ìlú Abuja ni ago méjì kọjá iṣẹ́jú mẹ́ẹ̀dógún ní ọsán nígbà tí o Gbàlejò àwọn ènìyàn nípa eré ìdárayá.

Aare ṣe àpèjúwe eré ìdárayá náà gẹ́gẹ́ bíi èyí to ni agbára to di ààmì réré láwùjọ.

Comments are closed.

button