Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Asòfin Ìpínlẹ̀ Kwara Buwólu Ìyànsípò Kọmísọ́nà Méjì

124

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀, Kwara ti buwólu ìyànsípò Mariam Nna Fatimah láti ìjọba Ìbílẹ̀ Edu àti Ọ̀mọ̀wé Lawal Ọlalekan Ọlọrungbẹbẹ láti ìjọba ìbílẹ Iwọ̀ Òrùn Ilọrin gẹ́gẹ́ bi Kọmísọ́nà ìgbìmọ̀ ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara

 

Ìbuwọ́lu ìyànsípò náà wáyé ní gbọ̀ngàn ilé Asòfin Ìpínlẹ̀ Kwara ní Ọjọ́rú níbi tí adarí Ilé Asòfin Onímọ̀-ẹ̀rọ Yakubu Danladi Salihu ti ka ìwé àtẹ̀jísẹ́ Gómìnà èyí tí ó bèèrè fún ìbuwọ́lù ìyànsípò àwọn ènìyàn náà láti ọwọ́ ilé asòfin

 

Àwọn ènìyàn méjéèjì náà ni wọ́n fi arahàn fún àyẹ̀wò fín-ní-fín-ní, lẹ́yìn náà ní ilé buwọ́lu ìyànsípò wọn

Comments are closed.

button