Take a fresh look at your lifestyle.

Aṣáájú Nàìjíríà Gbá Àkọlé Àṣà Ìbílẹ̀ Tó Gíga Jùlọ Ní Akwa Ibom ‎

Lekan Orenuga

314

Ìgbìmọ̀ Àwọn Alàkóso ìbílẹ̀ tí Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom tí ṣé ọla fún Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu pẹ̀lú àkọlé tó gá jùlọ tí “Otuekong,” èyí tó ṣàfihàn Ààrẹ gẹ́gẹ́bí Alàkóso àgbà ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom.

‎ Ibù-ọlá fún Ààrẹ náà ló wáyé ní ọjọ́ Ẹtì ní ilé-ìjọba àpapọ́ ní Abùjá.

‎ Ààrẹ Tinubu sọ ìlọsíwájú ní ìpínlẹ̀ Akwa Ibom sí ìríran àti ìfaramọ́ sí ètò ìdàgbàsókè ajumọṣe.

‎ Aṣáájú Nàìjíríà sọ pé orílẹ̀-èdè náà yóò tẹ̀síwájú ní tí dáadáa nígbà tí àwọn aṣáájú òṣèlú bá ríran tayọ ìdúróṣinṣin pẹ̀lú ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ àti sísìn orílẹ̀-èdè wọ́n.

Comments are closed.

button