Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Ṣèlérí Láti Dúró Fún Ètò Ọrọ-Àjé Tó Dára Fún Nàìjíríà

Lekan Orenuga

207

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí ṣèlérí láti ṣé ìtọ́jú ètò ọrọ-àjé Nàìjíríà, èyítí yóò ṣé adínkù nínú owó oúnjẹ, pàápàá júlọ l’àkókò àwẹ Ramadan yìí.

‎ Ààrẹ Tinubu sọ èyí lásìkò tó n sọrọ níbí ìpàdé Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ tí ẹgbẹ́ òṣèlú tí ‘All Progressives Congress (APC),’ ní Olu-Ile ẹgbẹ́ wọ́n ní Abuja.

‎ O sọ pé èyí jẹ́ apa kan nínú àwọn akitiyan ìṣàkóso rẹ̀ láti kojú ètò ọrọ ajé àti ìnáwó.

‎ Ààrẹ náà wá ṣàfihàn ìlọsíwájú tí orílẹ̀-èdè náà lórí ààbò, ààbò oúnjẹ, àti ètò-ọrọ àjé, Ó n sàlàyé yí nínú idupẹ rẹ̀ fún àwọn àṣeyọrí ìdìbò tí ẹgbẹ́ náà àti gbígba àwọn ọmọ ẹgbẹ́ túntún sí àpéjọ náà.

Comments are closed.

button