Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Katsina Jẹ́jẹ̀ẹ́ Láti Se Ètò Ìdìbò Ìjọba Ìbílẹ̀ Tí Kò Ní Ẹja-n-bákàn Nínú

164

Gómìnà Ìpínlẹ Katsina, Dikko Umaru Radda ti ké sí ẹgbẹ́ òsèlú APC àti àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ nínú ẹgbẹ́ náà láti pèpè àtìlẹyìn fún ẹgbẹ́ náà lójúnà àti jáwé olúborí nínú ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ tí ó ń bọ̀ níwájú

 

Ó sọ ọ̀rọ̀ náà níbi ìpàdé ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ náà tí ó wáyé ní gbàgede ilé iṣẹ́ ìjọba, ní ìlú Katsina. Gómìnà Radda pàrọwà sí àwọn ti ọrọ kan lati siṣẹ takuntakun fun ìjáwé olúborí ẹgbẹ́ náà

 

Ó jẹ́jẹ̀ẹ́ ètò ìdìbò tí kò ní tàbí-sùgbọ́n nínú, àtipé ètò ìdìbò náà yóò lọ ní ìrọwọ́-rọsẹ̀

 

Comments are closed.

button