Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano Pàrọwà Sí Àwọn Adájọ́ Tuntun Fún Ìsàgbékalẹ̀ Ìdájọ́ Òdodo

118

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abba Yusuf ti pàrọwà sí àwọn adájọ́ mẹ́tàlá tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ búrafún láti tẹ̀lé àlàkalẹ̀ òfin ìdájọ́ pẹ̀lú mímú ìsàgbékalẹ̀ ìdájọ́ òdodo ní ọ̀kúkúdùn

 

Gómìnà gbàwọ́n nímọ̀ràn nígbà tí wọ́n ń se ìbúra fún àwọn adájọ́ mẹ́sàn-án fún ilé ẹjọ́ gíga ati awọn mẹ́rin míràn fún ilé ẹjọ́ Sharia, ní ọ́ọ́fìsì ìjọba ìpínlẹ̀ Kano

 

Ó gbàwọ́n níyànjú láti tẹ̀síwájú nínú ojúse wọn láti fi ìdájọ́ àti àlàkalẹ̀ òfin múlẹ̀, èyí tí yóò kó iyì bá ètò ìdájọ́ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lápapọ̀

 

Comments are closed.

button