Take a fresh look at your lifestyle.

Ènìyàn Mọkánlèlógójì Ni Ó Fi Ojú Ba Ilé Ẹjọ́ Látàrí Ìwakùsà Lọ́na Àìtọ́ Ní Ìlú Ibadan- Àjọ Ọlọ́pàá

113

Ènìyàn mọ́kànlélógójì ni ó fi ọwọ́ pọn ẹ̀yìn rojọ́ ní ilé ẹjọ́ gíga ti ìlú Ibadan, ìpínlẹ̀ Ọyọ, ní Ọjọ́bọ̀, látàrí ẹ̀sùn ìwakùsà lọ́nà àìtọ́

 

Àwọn olùjẹ́jọ́ náà ni wọ́n fi ẹ̀sùn méjì kàn, ẹ̀sùn ìlẹ̀dí-àpò-pọ̀ sebi àti ìwakùsà lọ́nà àìtọ́, níwájú adájọ́ Uche Agomoh

 

Agbejọ́rọ̀ fún àwọn ọlọ́pàá, ọgbẹ́ni Micheal Ojeah sàlàyé fún ilé ẹjọ́ pé, ọwọ́ tẹ àwọn afurasí mọkanlelogoji naa ni ọjọ kẹẹ̀dọ́ọ́gbọ̀n osù kini, ni abule Onipanu, ilu Ibadan nigba ti wọn ledi apo pọ lati wa kusa lọna ti ko ba ofin mu

 

 

 

Comments are closed.

button