Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Pè Fún Ìtúsílẹ̀ Àwọn Tí Ó Wà Ní Ìgbèkùn Agbésùmọ̀mí Ní Kíá-kíá

152

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu pàṣẹ fún àwọn agbófinró láti wá ọ̀nà àbáyọ fún ìtúsílẹ̀ àwọn ènìyàn tí ó wà ní ìgbèkún àwọn agbésùmọ̀mí ní ìpínlẹ̀ Borno àti Kaduna

 

Ààrẹ pàṣẹ ọ̀rọ̀ náà ní ọjọ́ Ẹtì nínú ìfiléde kan ti agbenusọ ààrẹ Ajuri Ngalale fi ọwọ́ sí

Ó pàṣẹ ìjìyà tí ó yẹ fún àwọn oníṣẹ́ láabi náà, ó sì bu ẹnu àtẹ́ lu ìwà ìgbésùmọ̀mí èyí tí ó wáyé ní ìpínlẹ̀ Borno àti Kaduna

Comments are closed.

button