Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Kẹ́dùn Ikú Àgbà Ọjẹ̀ Bánkì, Wigwe

255

Ìgbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ní Ọjọ́rú ṣọfọ ìkú Alákóso tí Access Holdings Plc, Herbert Wigwe, àtí ẹbí rẹ̀.

Wigwe ló kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ Òfurufú kàn ní America.

Ìgbákejì Ààrẹ Shettima, nínú irin ìyìn rẹ̀, ṣàpèjúwe Olóògbé Wigwe gẹ́gẹ́ bí ìjí òwúrọ̀ kùtùkùtù tó yí àwọn ètò Ilè ifowopamọ Nàìjíríà pàdà, bí ó tí ṣé ìrántí òye àti ìmọ rẹ̀ ní àgbègbè náà.

Comments are closed.

button