Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ òsìsẹ́ NLC Ṣe Ètò Ìwọ́de Nílùú Abuja

162

Awọn Ẹgbẹ Oṣiṣẹ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà ṣe iwọde lonii ọjọ kẹtadinlọgbọn lori bi ọrọ ilu yii ṣe n lọ

Wọn ke si Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu lati wa nkan ṣe si gbogbo ohun ti o n ṣẹlẹ yìí, Bi Ounjẹ ṣe n gbe owo lori, ni epo naa n ṣe ti rẹ

Ninu patako ti wọn gbe lọwọ lati ri awọn nkan ti wọnkọ bíi Oju ti àwọn ọ̀tá Nàìjíríà, Tinubu n tun Nàìjíríà ṣe, ati bẹẹ bẹẹ lọ

Awọn DSS naa wani bẹ pẹ̀lú

Bí ẹgbẹ́ òsìsẹ́ NLC se ń parí ètò ìwọ́de wọn nílé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ni àwọn ẹgbẹ́ kan náà gbé ìwọ́de wọn wá sílé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ìlú Abùjá láti wá se àtìlẹ́yìn fún ìjọba ààrẹ Ahmed Bola Tinubu fún àwọn ìgbìyànjú rẹ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà

Comments are closed.

button