Ààrẹ Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu tí ṣètò ìgbìmọ̀ Olùdámọ̀ràn ètò-ọ̀rọ̀ àjé kan tó kó àwon aṣojú tí ìjọba àpapọ̀, àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè kàn àtí àwọn onílè ìṣẹ́ aládáni
Èyí ní àbájáde àwọn ìjìròrò tó wáyé ní ìrọ́lẹ́ ọjọ́ Àìkú láàrín Ààrẹ àtí àwọn alẹnú-lọrọ̀ pàtàkì ní Ilè Ìjọba ní Abuja.
Nígbàtí o nsọ̀rọ ní ìpàdé náà, Ààrẹ Tinubu sọ pé ìdí pàtàkì fún ìpàdé náà ní látí ṣé àfikún ìgbìyànjú láti kojú ètò-ọ̀rọ̀ àjé àti ìdánilójú ọjọ́ iwájú fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Àlàyé mbọ̀ lẹkunrẹrẹ…