Alákóso ‘4 Special Forces Command’ tí àwọn ọmọ-ogún tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí fún àwọn òṣìṣẹ́ Ọmọ-ogún márùn fún iṣẹ́ ríbiríbi tí wọ́n ń ṣé ní ẹnú iṣẹ́ wọ́n.
Alákóso, Major General Hillary Nzan sọ pé ẹbùn yí wà látí ṣé ìwúrí fún wọ́n àtí àwọn òṣìṣẹ́ mìíràn látí tẹ́ ipamọ ṣẹ́

Nígbàtí o nsọ̀rọ níbí ‘West African Social Activities’ (WASA), ní ‘4 Special Forces Command,’ tí ìjọba ìbílẹ̀ Doma ní ìpínlẹ̀ Nasarawa, Major Hillary Nzan sọ pé WASA jẹ́ ọkàn nínú àwọn ẹ̀ka tó ṣàfihàn àwọn àṣà tí àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà.

Ayẹyẹ náà ní ó máa ń wáyé ní ọdọọdún níbí tí àwọn òṣìṣẹ́ ọmọ-ogun, àwọn ìdílé wọ́n, àti àwọn àlejò látí s’ami sí ìparí àwọn iṣẹ́ fún ọdún náà.