Take a fresh look at your lifestyle.

Olùdíje Sí Ipò Gómìnà Méjì Nínú Ẹgbẹ́ Òsèlú APC Juwọ́ Sílẹ̀

193

Olùdíje sí ipò gómìnà méjì lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú APC ti fi ọwọ́ sílẹ̀ nínú ìdìbò tí ìrètí wà pé yóò wáyé ní ọjọ́ kọkànlá osù kẹsàn-án ọdún 2024

 

Igbákejì gómìnà tẹ́lẹ̀rí ní ìpínlẹ̀ Edo, Lucky Imasuen àti òsìṣẹ́ fẹ̀yìntì lẹ́nu iṣẹ́ ìjọba, Ọ̀mọ̀wé Ernest Umahikhe ti kéde ìjuwọ́sílẹ̀ wọn nínú àtẹ̀jáde ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ìlú Benin, ní ọjọ́ Àìkú

 

Imusen sàlàyé pé ìjuwọ́sílẹ̀ náà wáyé látàrí  ìmọ̀ràn àwọn alákòóso ẹgbẹ́ òsèlú APC tí ó fi ipò naa si aarin gbingbin Edo

 

 

Comments are closed.

button