Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Yóò Kó Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Dé Ilẹ̀ Ìlérí- Igbákejì Ààrẹ Shettima

190

Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ti wòye pé Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti ń là kààkà láti mú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dé ilẹ̀ ìlérí

 

Gẹ́gẹ́ bí ó se sọ, pẹ̀lú ìgbìyànjú, ìfarajì, àti òtítọ́ inú, ìrètí wà pé ọjọ́ iwájú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò dára

 

Ó wá sàfirinlẹ̀ ipa àwọn oníròyìn gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó se pàtàkì láti mú kí Orílẹ̀-èdè tẹ̀síwájú.

 

Comments are closed.

button