Gbajúgbajà Akọrin ti wọn bọwọ fún gidigidi ọmọ Naijiria, Timi Dakolo ti gbe orin tuntun kẹta jade, to pe akole re ni, ‘The Chorus Leader’.
Wọ́n bíi láti ipinlẹ Bayelsa ni Gusu Nàìjíríà, Timi Dakolo ti lù aluyo nidi Ise orin lati nnkan bi ogun odun sẹ́yìn ti àwọn ololufẹ rẹ sí fẹràn rẹ latari orin rẹ̀ tó ba ìgbà, asa abbl mu.
Àwọn Tíràkì to wa nínú “Chorus Leader” náà niyi:
Premium Enjoyment
Obim ft. Ebuka, Noble Igwe
Anything for You
Ke Ne Ke So
Omo Ayo
Nothing Dey Spoil for God Hand
Na So E Be ft. Patoranking
No Forget Home
Happy Fellows
Hard Guy
One Day
Men of the South
This Woman ft. Phyno, Falz, Cobhams Asuquo, Black Geez
Hustle
Amen
Iyawo Mi
The Vow
Tèmítọ́pẹ́ Òbíẹ̀esan