Take a fresh look at your lifestyle.

Ọwọ́ Sìkún Àjọ Ológun Tẹ Ọ̀bàyéjẹ́ Kan Tí Ó Gbé Oògùn Olóró

150

Adarí ikọ̀ Ọmọ Ogun ẹlẹ́ẹ̀karùnlélọ́gbọ̀n, Ọ̀gágun Mohammed Tajudeen Aminu ti kó oògùn olóró èyí tí ó dín díẹ̀ ní igba kìlógíráàmù fún àjọ NDLEA, ẹka ti ipinlẹ Ogun

 

Ọwọ́ àjọ ológun tẹ afurasí náà ní ọjọ́ kẹfà osù kíní ọdún 2024 ni Olodo Imeko, òpópónà Imekọ si Abẹokuta

 

Àjọ omọ ogun safirinlẹ igbaradi rẹ lati tẹsiwaju ninu ipa rẹ̀ láti fọwọsowọ́pọ pelu agbofinro yoku lati se afọmọ ipinle Ogun kuro lọwọ awọn oníṣẹ́ laabi ti o n sowo Oogun oloro naa.

 

Comments are closed.

button