Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Àgbà ti parí ètò láti sọ àbádòfin ìsúná ti ọdún 2024 di òfin ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọgbọ̀n ọjọ́ osù kejìlá ọdún 2024
Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu gbé àbá ìsúná tírílíọ̀nù mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n àbọ̀ síwájú ilé ìgbìmọ̀ asòfin nínú osù kọkànlá, tí ó sì bèrè fún ìfọwọ́sí ilé ìgbìmọ̀ asòfin kí ọdún tó parí
Ìrètí wà pé ní déédé agogo mẹ́wàá òwúrọ̀ ọjọ́ Àbámẹ́ta ní ètò náà yóò bẹ̀rẹ̀.