Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Yóò Ṣé Àgbéyẹ̀wò Àwọn Ètò Ìlànà Ilẹ̀ Òkèèrè Tí Nàìjíríà Pẹ̀lú Ifojusi To Ìjọba Tiwá-Ń-Tiwá – Mínísítà

228

Mínísítà fún ètò Ọrọ̀ ìlẹ̀ Òkèèrè tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Yusuf Tuggar, tí sọ pé ètò ìmúlò ilẹ̀ òkèèrè tí orílẹ̀-èdè náà nílò ìfọkànsí lórí líló ọgbọ̀n látí ṣé àṣeyọrí lórí ifi ipá gbájọba ní Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà àti ilẹ̀ Áfíríkà lápapọ̀.

O sọ èyí làkókò tó n sọ àsọye lórí “Àgbékalẹ̀ Ètò ìmúlò ilẹ̀ òkèèrè lábẹ́ Ìṣàkóso Tinubu,” níbí ìpàdé Ọlọdọọdún àwọn aṣojú Nàìjíríà tó tí f’ẹyin tì ‘Annual Association of Retired Career Ambassadors of Nigeria (ARCAN)’ ní Abuja, Nàìjíríà.

Gẹ́gẹ́ bí Mínísítà náà, ètò ìmúlò ilẹ̀ òkèèrè tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní á tún ní ìfọkànsí láti ríi dájú pé orílẹ̀-èdè náà gbá ìjoko níbí Ìgbìmọ̀ Ààbò Àgbáyé (UN), àwọn àjọ àgbáyé mìíràn àtí àwọn ilé-iṣẹ́

Comments are closed.

button