Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ipinle Rivers ti jáwọ́ kúrò nínú fífún Gómìnà Siminialayi Fubara ni ìwé láti kúrò lórí àlééfà.
Agbẹnusọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, Martin Amaewhule ló fi èyí léde ni ọjọ́ Ọjọ́rú ní ìlú Port Harcourt..
Agbenuso náà sọ pé èyí rí bẹ látàrí pé ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti dá sí ọ̀rọ̀ náà.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san