Take a fresh look at your lifestyle.

NPFL Bèèrè Fún Ìgbà Láàyé Ọ̀pọ̀ Àwọn Àgbábọ́ọ̀lù Rẹ̀ Nínú Ẹgbẹ́ ‘Super Eagles’

0 263

Ìgbìmọ̀ Bọ́ọ̀lù afẹsẹgba Nàìjíríà (Nigeria Premier Football League NPFL) ń pé fún ìgbà láàyè ọ̀pọ̀ àwọn àgbábọ́ọ̀lù NPFL nínú ìkọ ‘Super Eagles,’ ní ìgbìyànjú láti mú ìlọsíwájú bá Lìígì àtí àwọn àgbábọ́ọ̀lù.

Ìgbìmọ̀ náà sọ pé lílò àwọn ìrawọ àgbábọ́ọ̀lù náà nínú ìkọ orílẹ̀-èdè yóò ṣé ìwúrí fún àwọn tó ní ìrètí láti fí Orílẹ̀-èdè náà sílẹ̀ dúró, dipo wíwá àwọn ẹgbẹ́ mìíràn nílẹ̀ òkèèrè. Làkókò tó ṣé ìwúrí ọ̀pọ̀lọ́ àwọn àgbábọ́ọ̀lù òkèèrè, Ìgbìmọ̀ NPFL gbàgbọ́ pé ó yẹ́ kí wọ́n pèsè ayé fún àwọn ọ̀pọ̀lọ́ nínú ìdíje rẹ̀.

Nínú ìfọ̀rọ̀wérọ̀ kàn lẹyìn àfihàn àwọn adari ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù NPFL àti àwọn òṣìṣẹ́ nínú ìpàdé kàn nílu Abuja, eléyìí tí Ààrẹ àjọ àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà, Ibrahim Gusau, wà nílùú Abuja.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button