Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ẹjọ́ Gíga Ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ti Fi Àyè Gba Níná Owó Náírà Àtijọ́ Àti Tuntun Laini Gbèdéke

0 188

Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fi àyè gba níná owó náírà tuntun àti ti àtijọ́ ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà èyí tí ó fagilé gbèdéke ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù kejìlá ọdún 2023 èyí tí ó ti wà tẹ́lẹ̀

 

Ilé Ẹjọ́ Àpapọ̀ se ìdájọ́ náà ní Ọjọ́rú níbi tí àwọn adájọ́ àgbà méje èyí tí adájọ́ Inyang Okoro darí ti sọ pé òfin fi àyè gba níná àwọn owó tí ó wà níta títí tí ìjọba yóò fi gbé ìgbésẹ̀ míràn lórí ọ̀rọ̀ náà

 

Ilé Ẹjọ́ se ìdájọ́ náà lẹ́yìn ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ tí amòfin àgbà tí ó jẹ́ Mínísítà Fún Ìdájọ́ òdodo, Ọmọba Lateef Fagbemi SAN se sí ilé ẹjọ́.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button