Ìgbésẹ̀ Ààrẹ Tinubu Lórí Ètò Ọrọ̀ Ajé Yóò So Eso Rere Fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà- Gómìnà Ìpínlẹ̀ Enugu
Gómìnà Ìpínlẹ Enugu, Peter Mbah ti sàpèjúwe ìgbésẹ̀ Ààrẹ Tinubu lórí ètò ọrọ̀ ajé gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó tọ́, tí yóò sì so èso rere fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Mbah tẹ̀síwájú pé ìgbésẹ̀ láti ní ọ̀nà ìpààrọ̀ owó kan soṣo ti ń so èsò rere fún ìpínlẹ̀ Enugu
Gómìnà fi ọ̀rọ̀ náà léde lẹ́yìn ìpàdé bòńkẹ́lẹ́ pẹ̀lú ààrẹ ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ Ìṣẹ́gun, ní ìlú Abuja.
Leave a Reply