Alága ẹgbẹ́ àwọn gómìnà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara, Mallam AbdulRahman AbdulRazaq ti gbóríyìn fún ìdájọ ilé ẹjọi tó ga jùlọ ní orílẹ̀-èdè yìí pé, ètò ìdìbò ààrẹ ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n oṣù Kejì, ọdún yìí, jẹ́ èròngbà ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn Nàìjíríà tó kópa nínú ètò ìdìbò náà, ìdájọ́ náà ti jẹ̀rí sí èyí.
Bi o se sọ, ìdájọ ile-ejo to ga jùlọ náà yóò mú kí ààrẹ ní agbára síi láti mú èròngbà rere rẹ̀- àtúnṣe ìrètí wá sí ìmúsẹ.
Ó wá ró gbogbo mùtú mùwà láti gbárùkọ ti ìjọba rẹ̀ láti tún orile-ede yi se kò sì jẹ orílẹ̀-èdè tó dára tó lọ́rọ̀.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply