Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí ṣé oríyin fún Dókítà Christopher Oladipo Ogunbanjo, OFR, OON, fún ìgbésí ayé tó dára pẹ̀lú ìdàgbàsókè àwọn àgbègbè, ìmọ̀ràn ìsọkan àti àlàáfíà láàárín àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ààrẹ Tinubu tún kẹdun pẹ̀lú ìdílé Ogunbanjo àti gbogbo ìlú Ìjẹ̀bú-òde nípa ikú alàgbà náà, Pa Ogunbajo tó ṣé ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn gẹ́gẹ́ bí agbẹjọro àgbà fún àwọn ilé-iṣẹ́.
Ìbànújẹ Ààrẹ wà nínú ọrọ̀ kàn tí agbẹnusọ rẹ̀, Ajuri Ngelale fọwọ́sí.
Ààrẹ Tinubu darapọ̀ mọ́ ọgọrọ àwọn ọmọ, ẹbí, ọrẹ àti àwọn ojúlùmọ̀ láti kẹdun ikú rẹ̀.
Leave a Reply