Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Yan Kọmití Asètò Fún Ọjọ́ Ìrántí Àwọn Ológun

0 282

 

Mínísítà ètò ààbò, ti rọ àwọn Kọmití tuntun ti wọ́n ṣẹṣẹ yàn láti ṣètò fún ìrántí awọn ọmọ ológun fún ti ọdún 2024 láti sa gbogbo ipá wọn láti se ayẹyẹ ìrántí àwọn akíkanjú ọmọ ológun to subú lójú ìjà.

Mínísítà dámọ̀ràn yi nígbà tí ó ń se ìfilọ́lẹ̀ ẹni mẹ́àalélógún ti yóò seto-National Planning Committee (NPC), kí wọn bẹ̀rẹ̀ ìpalèmọ́ láti jẹ́ kí ètò- Armed Forces Remembrance Day Celebration (AFRDC) odun 2024 kẹ́sẹ járí. Ó sọ fún wọn kí wọ́n ṣètò alárinrin láti yẹ́wọn sí.

Àyájọ́ ọjọ́ ìrántí ológun a máa wáyé ni ọjọ́ kẹẹ̀dógún, oṣù kínní ọdọọdún.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button