Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Gbóríyìn Fún Ilé-iṣẹ́ Àjọ Tó Ń Gbógun Tí Ìwà Ọ̀daràn

0 273

A tí gbóríyìn fún Àjọ tó ń rí sí ìwà ọ̀daràn, ètò ọrọ̀ ajé àti ìnáwó [EFCC] fún ṣíṣe àṣeyọrí tó wúni lórí nínú gbígbógun ti àwọn ìwà ọ̀daràn, ètò ọrọ̀ ajé àti ìnáwó.

Ààrẹ Bola Tinubu tó ṣé ìyìn náà tún pé fún àwọn akitiyan tó lágbára láti kojú ìwà ìbàjẹ́ náà.

Tinubu Gbóríyìn yìí fún wọ́n ní ìlú Abuja làkókò tó ń kéde ètò ìwà ọ̀daràn, ètò ọrọ̀ ajé àti ìnáwó ẹlẹ̀ẹ́kàrún ùn irú rẹ̀ (5th Economic and Financial Crimes Commission, EFCC – National Judicial Institute, NJI Capacity Building Workshop) fún ìdájọ́ àti àwọn onídájọ́.

Mínísítà fún ẹjọ́ àti ètò ìdájọ orílẹ̀-èdè yìí, Lateef Fagbemi tó ṣojú Ààrẹ sọ pé, àwọn ànfààní nlá tí wà nínú ìgbógun tí ìwà ìbàjẹ́ èyí tí Àjọ EFCC ṣiṣẹ́ takuntakun nínú àṣeyọrí náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button