Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Anambra Yí Orúkọ Pápákọ̀ Òfúrufú Padà Sí Orúkọ Chinua Achebe

0 205

 

Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Soludo ti yi orúkọ pápákọ̀ òfúrufú ti ìpínlẹ̀ náà padà sí orúkọ ti Ọ̀jọ̀gbọ́n Chinua Achebe.

Èyí jẹyọ níbi ọ̀rọ̀ ti Gómìnà sọ nibi ayẹyẹ ọdún òmìnira to wáyé lánàá ọjọ́ Kínní oṣù Kẹwàá, ọdún 2023.

Gómìnà wòye pé, Ọ̀jọ̀gbọ́n Achebe kọ àmì ẹ̀yẹ ti orílẹ̀-èdè yìí fi dá lọ́lá ní ìgbà méjì, ti àwọn ri pé kò tọ̀na fún ìpínlẹ̀ Anambra, sugbon báyìí ìpínlẹ̀ Anambra ti dáa lọ́lá.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button